

Ọlọ́run tó dá wọn
Ó ké ìgbà ni
Ẹ̀yin ni
mo fi ọpẹ́
Ẹ̀mi fún
Ọlọ́run tó dá wọn
Ó ké ìgbà ni
Ẹ̀yin ni
mo fi ọpẹ́ Ẹ̀mi fún
Ta ní wọn tún gbé ga o
Bí kò ṣe baba lókè
Ta ní wọn tún fi gbogbo Ọpẹ́ mi fún
Ọlọ́run tó dá wọn
Ó ké ìgbà ni
Ẹ̀yin ni
mo fi ọpẹ́
Ẹ̀mi fún
Ọlọ́run tó dá ọ̀run
òun ayé
Ọwọ́ ni ìforúkọ rẹ̀
Baba mi ló lọ́kọ̀ tí wá kọ́
ọ̀rẹ́
Ó sì mọ̀ wípé mo wà nínú ọkọ̀ ọlọ́run
Ọlọ́run tó dá wọn
Ó ké ìgbà ni
Ẹ̀yin ni
mo fi ọpẹ́
Ẹ̀mi
fún
Gbè orí mi sórí
òkè wọn ni
Níbo ni
ìránlọ́wọ́ mi ẹ̀yin ti wá Ìránwọ́ mi ó tọwọ́
Elédùmarè wá
Tó dá ọ̀run òun
ayé
Ọlọ́run tó dá wọn
Ó ké ìgbà ni Ẹ̀yin ni
mo fi ọpẹ́
Ẹ̀mi fún